YIYA FUN IṢẸJU MARUN
Ní Ọwọ́ Rẹ Ló Wà

Ṣé ọlọ́wọ́ òtún ni ọ́tàbí i ọlọ́wọ́ àlàáfíà? Ṣé o lè lo ọwọ́ rẹ méjèèjì láti kọ̀wé tàbí ya  àwòrán? 

Gbìyànjú láti lo ọwọ́tí o kìí ń fi ìgbà gbogbo lò. 

1.Gbìyànjú láti lo ọwọ́tí o kìí ń fi ìgbà gbogbo lò. 

2.Ṣe àgbékalẹ̀ sínú àwòrán ọwọ́ rẹ náà.  

3. Pa àgbékalẹ̀ àwòrán ọwọ́ rẹ pọ̀mọ́ti ọ̀rẹ́ rẹ kí ó lè di ńlá !

4. Ya ọwọ́ rẹ yíká. Oríṣi ẹranko mélòó ni o lè gbé jáde nínú ìrísí ọwọ́ rẹ?

Copyright Polly Alakija