GIGE GIGE

Gbogbo wa la nífẹ́ gigé àwọn nǹkan!
Ṣùgbọ́n sé gbogbo wa ní o leè gé nǹkan bi o se ye?

Sa ìwé kékeré àti káàdi àtijọ́ láti inu àpόti jọ́, fa àwọn ilà ti ọmọ rẹ leé máa tẹ̀lé pẹ̀lú lati máa gé irú àwon káàdi yii.
Bẹ̀rẹ̀ ni irọrùn pẹ̀lú diẹ̀ nínú àwọn ilà lainí wàhalà, lẹ́yin náà jẹ́ ki o nípènijà diẹ̀ síi, pẹ̀lú àwọn ẹkὸrὸ.

Copyright Polly Alakija