HIHUN ITÀN : ODUN OMI WA

Sa àwọn àgékù aṣọ, okùn, títẹle ara, àti àwọn ilẹ̀kẹ̀ jọ.
Se àranpọ̀ wọn láti sọ àwọn itàn rẹ. Jẹ ìgbádùn didáṣe àwọn àran tuntun láti ṣe àwọn ilànà oríṣiriṣi.

Odún Omi Wa.

Fún oṣù kọ̀ọ̀kan, se àran itàn omi kan.
Ẹ̀ẹ̀mélὸό ní ὸjὸ rọ̀ nínú osù yii?
Ṣe odὁ kún?

Ẹbí kọ̀ọ̀kan leè ṣe kẹkẹ onígun mẹ́rin oríṣiriṣi àti lẹ́yin náà rán gbogbo wọn papọ̀ láti ṣe ohun ọ̀ṣọ́ dáradára fún ilé rẹ.

Copyright Polly Alakija