KINÍ KINÍ OHUN TI O LO OMI FÚN LὁὸNÍ?
Ṣe àpẹrẹ kan fún lilo omi ojὁojύmọ́ ti àwọn ẹbí rẹ.
Lὁjoojύmọ́ ya àwὸrán ohun ti o n lo omi fún.
Ṣe o:
mύ? Fọ eyin rẹ? Fọ ọwọ́ rẹ? Fọ aṣọ? Fomi rin oko?
Ṣe o leè sọ itàn omi ẹbí rẹ nínú pẹ̀lú àwọn àwὸrán?