ORÍN ÀTI ILÙ NÍPA OǸKÀ
Sa diẹ̀ nínú àwọn ìgὸ àtijọ́ jọ.
Rọ omi sí ìgὸ kọ̀ọ̀kan sí àwọn ipèlé oríṣiriṣi.
O leè kun àwọn omi náà ni àwọ̀.
ZOBO ni a fi kun àwọn omi ìgὸ orín tiwa ni àwọ̀.

Bi omi ba se pọ̀ tό ni àwọ̀ re yόὸ se se fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ tό.

Bi omi ba se pọ̀ tό nínú ìgὸ ni ohùn orin yόὸ se kéré tό nígbàti a bá fi ọwọ́ kàn án.
Fi oǹkà si àwọn ìgὸ orín rẹ láti 0-9.


Copyright Polly Alakija
Ṣe o leè ṣe orín aládùn fún àwọn ọmọ rẹ láti ṣeré?