Ọ̀RỌ̀ SISỌ PORT HARCOURT

Káàbọ̀ Onyinye!  Nnoo Onyinye!

Port Harcourt ni olú-ilú ti Ipinlẹ̀ Rivers.

Copyright Polly Alakija

Ipinlẹ̀ Rivers kún fún ODὁ! sO tún kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oríṣiriṣi èdè abiníbi..O tún ń jẹ́ Ipinlẹ̀ ọ̀ọ́dúnrún èdè”.Láti jijẹ́ agbègbè apeja, Port Harcourt di agbègbè pàtàki ti gbigbé ọjà èédú lọ sí ilẹ̀ ὸkèèrè nígbà Ijọba amúnisin àti lẹ́yin náà epo rọ̀bi. Èyi túmọ̀ sí pé Port Harcourt ti di ilú ńlá.

Copyright Keith Arrowsmith

O tún leè ri diẹ̀ nínú àwọn ilé amunísín àtijọ́ ní Port Harcourt.

Bole àti ẹja jẹ́ ounjẹ́ idàpọ̀ ti ọ̀gẹ̀dẹ̀ tàbi iṣu sísun àti ẹja sísun ti a njẹ pẹ̀lú ipẹ̀tẹ̀ epo ọ̀pẹ. Ní Port Harcourt, oúnje yii wà gẹ́gẹ́ bi ipanu tàbi nigbà miiràn, o leé dúrό bi ounjẹ́ àkọ́kọ́.

Copyright Sharpsooters

Àti pé gbogbo ènìyàn lό nífẹ́ẹ́ ọkọ̀ ojύ omi ní Ipinlẹ̀ Rivers..Ní oṣù kárùn ύn àwọn tí ό ní ọkọ̀ ojύ omi máa n seré ìdíje ti Port Harcourt Boat Regatta.

Copyright Daily Times

.Ipinlẹ̀ Rivers ní a mọ̀ ní Ipinlẹ̀ ti ẹgbẹ̀rύn egύngύn. Ní Port Harcourt, ní gbogbo oṣù kejilà ní ayẹyẹ ọdọọdύn máa n wáyé. Gbogbo ènìyàn ní ό máa n jáde láti ṣe ayẹyẹ àṣà ti Ipinlẹ̀ Rivers.

Copyright Finelib.com