PATAKI OHUN ELὸ Ẹ̀KỌ́

O leè ṣe àwọn ohun èlὸ ẹ̀kọ́ ti o dára jùlọ ní ilé, pẹ̀lú àwọn ohun ti o le rii ní ilé.

Àwọn ọmọ rẹ le ṣe irànlọ́wọ́ láti ṣe wọ́n pẹ̀lú!

Sa gbogbo àwọn ìke omi àtijọ́ rẹ àti àwọn idéri ìke omi jọ.

O leè ṣe àwọn káàdi nọ́mbà ọlọ́sọ̀ọ́ nípa lilo irú àwọ̀ àti aṣọ ti o wù ọ́.

.Àwọn ọmọ rẹ gbọdọ̀ rii dájú pé wọ́n tọ́jú iye nọ́mbà àwọn idéri ìgὸ pẹ̀lú nọ́mbà káàdi.

Copyright Polly Alakija