TA NÍ O PỌN OMI PÚPỌ̀ JULỌ NÍNÚ ILE RẸ? Pada Ṣe àwὸṣe kékeré ti ilé rẹ lόrí ìwé ti ό ṣόfo. Fi ààyè sílẹ̀ fún ẹni kọ̀ọ̀kan nínú ẹbí láti kọ bi wọn ṣe n gbà àti lo omi lόjoojύmọ́. Ní ὸpin ọ̀sẹ̀, ṣe àrὸpọ̀ gbogbo wọn! Copyright Polly Alakija